Jẹ́nẹ́sísì 49:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 “Sébúlúnì+ yóò máa gbé ní etíkun, ní èbúté tí àwọn ọkọ̀ òkun gúnlẹ̀ sí,+ ààlà rẹ̀ tó jìnnà jù yóò sì wà ní ọ̀nà Sídónì.+
13 “Sébúlúnì+ yóò máa gbé ní etíkun, ní èbúté tí àwọn ọkọ̀ òkun gúnlẹ̀ sí,+ ààlà rẹ̀ tó jìnnà jù yóò sì wà ní ọ̀nà Sídónì.+