- 
	                        
            
            Jẹ́nẹ́sísì 37:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        5 Nígbà tó yá, Jósẹ́fù lá àlá kan, ó sì rọ́ ọ fún àwọn arákùnrin+ rẹ̀, èyí mú kí wọ́n túbọ̀ kórìíra rẹ̀. 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            Jẹ́nẹ́sísì 37:8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        8 Àwọn ẹ̀gbọ́n rẹ̀ sọ fún un pé: “Ṣé o wá fẹ́ jọba lé wa lórí ni, kí o wá máa pàṣẹ fún wa?”+ Ìyẹn wá mú kí wọ́n túbọ̀ kórìíra rẹ̀, torí àwọn àlá tó lá àti ohun tó sọ. 
 
-