Jẹ́nẹ́sísì 35:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Ísákì wá mí èémí ìkẹyìn, ó sì kú, wọ́n kó o jọ pẹ̀lú àwọn èèyàn rẹ̀,* lẹ́yìn tó ti pẹ́ láyé, tí ayé rẹ̀ sì dáa;* Ísọ̀ àti Jékọ́bù ọmọ rẹ̀ sì sin ín.+ Jẹ́nẹ́sísì 49:33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 33 Nígbà tí Jékọ́bù fún àwọn ọmọkùnrin rẹ̀ ní ìtọ́ni wọ̀nyí tán, ó ká ẹsẹ̀ rẹ̀ sórí ibùsùn, ó mí èémí ìkẹyìn, wọ́n sì kó o jọ pẹ̀lú àwọn èèyàn rẹ̀.*+
29 Ísákì wá mí èémí ìkẹyìn, ó sì kú, wọ́n kó o jọ pẹ̀lú àwọn èèyàn rẹ̀,* lẹ́yìn tó ti pẹ́ láyé, tí ayé rẹ̀ sì dáa;* Ísọ̀ àti Jékọ́bù ọmọ rẹ̀ sì sin ín.+
33 Nígbà tí Jékọ́bù fún àwọn ọmọkùnrin rẹ̀ ní ìtọ́ni wọ̀nyí tán, ó ká ẹsẹ̀ rẹ̀ sórí ibùsùn, ó mí èémí ìkẹyìn, wọ́n sì kó o jọ pẹ̀lú àwọn èèyàn rẹ̀.*+