Ìṣe 7:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Jékọ́bù lọ sí Íjíbítì,+ ó sì kú síbẹ̀,+ ohun kan náà ló ṣẹlẹ̀ sí àwọn baba ńlá wa.+