-
Jẹ́nẹ́sísì 37:18Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
18 Wọ́n rí Jósẹ́fù tó ń bọ̀ ní ọ̀ọ́kán, àmọ́ kó tó dé ọ̀dọ̀ wọn, wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí í gbìmọ̀ pọ̀ kí wọ́n lè pa á.
-
-
Sáàmù 105:17Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
17 Ó rán ọkùnrin kan lọ ṣáájú wọn,
Jósẹ́fù, ẹni tí wọ́n tà lẹ́rú.+
-