Jẹ́nẹ́sísì 1:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ọlọ́run wá ṣe òfúrufú, ó pààlà sáàárín omi tó wà lókè òfúrufú náà àti omi tó wà ní ìsàlẹ̀ rẹ̀.+ Ó sì rí bẹ́ẹ̀. Jẹ́nẹ́sísì 8:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Àwọn orísun omi àti àwọn ibodè omi ọ̀run tì pa, òjò ò sì rọ̀ mọ́* láti ọ̀run.+
7 Ọlọ́run wá ṣe òfúrufú, ó pààlà sáàárín omi tó wà lókè òfúrufú náà àti omi tó wà ní ìsàlẹ̀ rẹ̀.+ Ó sì rí bẹ́ẹ̀.