Jẹ́nẹ́sísì 7:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Ní ọjọ́ kẹtàdínlógún oṣù kejì, ní ọdún tí Nóà pé ẹni ọgọ́rùn-ún mẹ́fà (600) ọdún, ọjọ́ yẹn ni gbogbo orísun omi ya, àwọn ibodè omi ọ̀run sì ṣí.+ Òwe 8:27, 28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Nígbà tó dá ọ̀run,+ mo wà níbẹ̀;Nígbà tó fi ààlà* sí orí omi,+28 Nígbà tó ṣe àwọsánmà sókè,*Nígbà tó dá àwọn ìsun ibú omi,
11 Ní ọjọ́ kẹtàdínlógún oṣù kejì, ní ọdún tí Nóà pé ẹni ọgọ́rùn-ún mẹ́fà (600) ọdún, ọjọ́ yẹn ni gbogbo orísun omi ya, àwọn ibodè omi ọ̀run sì ṣí.+
27 Nígbà tó dá ọ̀run,+ mo wà níbẹ̀;Nígbà tó fi ààlà* sí orí omi,+28 Nígbà tó ṣe àwọsánmà sókè,*Nígbà tó dá àwọn ìsun ibú omi,