Jẹ́nẹ́sísì 9:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Àwọn ọmọ Nóà tó jáde nínú áàkì ni Ṣémù, Hámù àti Jáfẹ́tì.+ Nígbà tó yá, Hámù bí Kénáánì.+ 1 Kíróníkà 1:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Nóà,+Ṣémù,+ Hámù àti Jáfẹ́tì.+