Jẹ́nẹ́sísì 5:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Ó pe orúkọ rẹ̀ ní Nóà,*+ ó sọ pé: “Ọmọ yìí á tù wá nínú* nídìí iṣẹ́ wa àti làálàá tí a ṣe torí ilẹ̀ tí Jèhófà ti fi gégùn-ún.”+
29 Ó pe orúkọ rẹ̀ ní Nóà,*+ ó sọ pé: “Ọmọ yìí á tù wá nínú* nídìí iṣẹ́ wa àti làálàá tí a ṣe torí ilẹ̀ tí Jèhófà ti fi gégùn-ún.”+