Jẹ́nẹ́sísì 1:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Lẹ́yìn náà, Ọlọ́run sọ pé: “Kí orísun ìmọ́lẹ̀*+ wà ní ojú ọ̀run, kí ìyàtọ̀ lè wà láàárín ọ̀sán àti òru,+ wọ́n á sì jẹ́ àmì láti fi mọ àwọn àsìkò, ọjọ́ àti ọdún.+ Sáàmù 74:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 O pa ààlà sí gbogbo ayé;+O ṣe ìgbà ẹ̀ẹ̀rùn àti ìgbà òtútù.+ Oníwàásù 1:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ìran kan ń lọ, ìran kan sì ń bọ̀,Àmọ́ ayé wà* títí láé.+
14 Lẹ́yìn náà, Ọlọ́run sọ pé: “Kí orísun ìmọ́lẹ̀*+ wà ní ojú ọ̀run, kí ìyàtọ̀ lè wà láàárín ọ̀sán àti òru,+ wọ́n á sì jẹ́ àmì láti fi mọ àwọn àsìkò, ọjọ́ àti ọdún.+