- 
	                        
            
            Jẹ́nẹ́sísì 8:22Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        22 Láti ìsinsìnyí lọ, ìgbà ìfúnrúgbìn àti ìgbà ìkórè kò ní tán ní ayé, bẹ́ẹ̀ ni òtútù àti ooru, ìgbà ẹ̀ẹ̀rùn àti ìgbà òtútù, ọ̀sán àti òru.”+ 
 
-