-
Jẹ́nẹ́sísì 10:32Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
32 Ìwọ̀nyí ni ìdílé àwọn ọmọ Nóà, bí wọ́n ṣe wà nínú ìdílé kálukú wọn àti orílẹ̀-èdè wọn. Ọ̀dọ̀ wọn ni àwọn orílẹ̀-èdè ti tàn káàkiri ayé lẹ́yìn Ìkún Omi.+
-