-
Jẹ́nẹ́sísì 9:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 Ní tiyín, ẹ máa bímọ, kí ẹ pọ̀, kí ẹ kún ayé, kí ẹ sì pọ̀ rẹpẹtẹ.”+
-
-
Jẹ́nẹ́sísì 9:19Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
19 Àwọn mẹ́ta yìí ni ọmọ Nóà, àwọn ló sì bí gbogbo èèyàn tó wà ní ayé, tí wọ́n sì tàn káàkiri.+
-