Ìsíkíẹ́lì 27:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Àwọn oníṣòwò Ṣébà àti Ráámà+ bá ọ dòwò pọ̀; wọ́n fi onírúurú lọ́fínńdà tó dáa jù, àwọn òkúta iyebíye àti wúrà ṣe pàṣípààrọ̀ ọjà lọ́dọ̀ rẹ.+
22 Àwọn oníṣòwò Ṣébà àti Ráámà+ bá ọ dòwò pọ̀; wọ́n fi onírúurú lọ́fínńdà tó dáa jù, àwọn òkúta iyebíye àti wúrà ṣe pàṣípààrọ̀ ọjà lọ́dọ̀ rẹ.+