Jẹ́nẹ́sísì 10:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Àwọn ọmọ Kúṣì ni Sébà,+ Háfílà, Sábítà, Ráámà+ àti Sábítékà. Àwọn ọmọ Ráámà sì ni Ṣébà àti Dédánì.