Jẹ́nẹ́sísì 15:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Àmọ́ ìran wọn kẹrin á pa dà síbí,+ torí ẹ̀ṣẹ̀ àwọn Ámórì kò tíì kún rẹ́rẹ́.”+ Diutarónómì 3:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 “Ìgbà yẹn la gba ilẹ̀ ọba àwọn Ámórì méjèèjì + tí wọ́n wà ní agbègbè Jọ́dánì, láti Àfonífojì Áánónì títí dé Òkè Hámónì+
8 “Ìgbà yẹn la gba ilẹ̀ ọba àwọn Ámórì méjèèjì + tí wọ́n wà ní agbègbè Jọ́dánì, láti Àfonífojì Áánónì títí dé Òkè Hámónì+