Jóṣúà 24:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Jóṣúà sọ fún gbogbo àwọn èèyàn náà pé: “Ohun tí Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì sọ nìyí, ‘Òdìkejì Odò* ni àwọn baba ńlá yín+ gbé ní ọ̀pọ̀ ọdún sẹ́yìn,+ ìyẹn Térà bàbá Ábúráhámù àti bàbá Náhórì, àwọn ọlọ́run míì ni wọ́n sì jọ́sìn.+
2 Jóṣúà sọ fún gbogbo àwọn èèyàn náà pé: “Ohun tí Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì sọ nìyí, ‘Òdìkejì Odò* ni àwọn baba ńlá yín+ gbé ní ọ̀pọ̀ ọdún sẹ́yìn,+ ìyẹn Térà bàbá Ábúráhámù àti bàbá Náhórì, àwọn ọlọ́run míì ni wọ́n sì jọ́sìn.+