Jẹ́nẹ́sísì 11:26, 27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Térà pé ẹni àádọ́rin (70) ọdún, ó sì bí Ábúrámù,+ Náhórì+ àti Háránì. 27 Ìtàn Térà nìyí. Térà bí Ábúrámù, Náhórì àti Háránì; Háránì sì bí Lọ́ọ̀tì.+
26 Térà pé ẹni àádọ́rin (70) ọdún, ó sì bí Ábúrámù,+ Náhórì+ àti Háránì. 27 Ìtàn Térà nìyí. Térà bí Ábúrámù, Náhórì àti Háránì; Háránì sì bí Lọ́ọ̀tì.+