Ìṣe 7:15, 16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Jékọ́bù lọ sí Íjíbítì,+ ó sì kú síbẹ̀,+ ohun kan náà ló ṣẹlẹ̀ sí àwọn baba ńlá wa.+ 16 Wọ́n gbé wọn lọ sí Ṣékémù, wọ́n sì tẹ́ wọn sínú ibojì tí Ábúráhámù fi owó fàdákà rà lọ́wọ́ àwọn ọmọ Hámórì ní Ṣékémù.+
15 Jékọ́bù lọ sí Íjíbítì,+ ó sì kú síbẹ̀,+ ohun kan náà ló ṣẹlẹ̀ sí àwọn baba ńlá wa.+ 16 Wọ́n gbé wọn lọ sí Ṣékémù, wọ́n sì tẹ́ wọn sínú ibojì tí Ábúráhámù fi owó fàdákà rà lọ́wọ́ àwọn ọmọ Hámórì ní Ṣékémù.+