-
Jẹ́nẹ́sísì 35:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 Torí náà, wọ́n kó gbogbo ọlọ́run àjèjì tí wọ́n ní àti àwọn yẹtí tó wà ní etí wọn fún Jékọ́bù, Jékọ́bù sì rì wọ́n mọ́lẹ̀* sábẹ́ igi ńlá tó wà nítòsí Ṣékémù.
-