ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jẹ́nẹ́sísì 28:16-19
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 Jékọ́bù jí lójú oorun, ó sì sọ pé: “Jèhófà wà níbí lóòótọ́, mi ò sì mọ̀.” 17 Ẹ̀rù wá ń bà á, ó sì sọ pé: “Ibí yìí mà ń bani lẹ́rù o! Ó ní láti jẹ́ pé ilé Ọlọ́run+ ni ibí, ẹnubodè ọ̀run+ sì nìyí.” 18 Jékọ́bù wá jí ní àárọ̀ kùtù, ó sì gbé òkúta tó gbórí lé, ó gbé e dúró bí òpó, ó sì da òróró sórí rẹ̀.+ 19 Ó wá pe orúkọ ibẹ̀ ní Bẹ́tẹ́lì,* àmọ́ Lúsì+ ni ìlú náà ń jẹ́ tẹ́lẹ̀.

  • Jẹ́nẹ́sísì 31:13
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 Èmi ni Ọlọ́run tòótọ́ tó bá ọ sọ̀rọ̀ ní Bẹ́tẹ́lì,+ níbi tí o ti da òróró sórí òpó tí o gbé sílẹ̀, tí o sì ti jẹ́ ẹ̀jẹ́ fún mi.+ Wá gbéra báyìí, kí o kúrò ní ilẹ̀ yìí, kí o sì pa dà sí ilẹ̀ tí wọ́n ti bí ọ.’”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́