ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jẹ́nẹ́sísì 13:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 Ábúrámù kúrò ní Íjíbítì lọ sí Négébù,+ òun àti ìyàwó rẹ̀ àti gbogbo ohun tó ní, pẹ̀lú Lọ́ọ̀tì.

  • Jẹ́nẹ́sísì 13:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 Ó ń pàgọ́ láti ibì kan dé ibòmíì lẹ́nu ìrìn àjò rẹ̀ láti Négébù lọ dé Bẹ́tẹ́lì, títí ó fi dé ibi tó pàgọ́ sí tẹ́lẹ̀ láàárín Bẹ́tẹ́lì àti Áì,+

  • Jóṣúà 7:2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 2 Jóṣúà wá rán àwọn ọkùnrin jáde láti Jẹ́rìkò lọ sí Áì,+ tó wà nítòsí Bẹti-áfénì, ní ìlà oòrùn Bẹ́tẹ́lì,+ ó sọ fún wọn pé: “Ẹ gòkè lọ ṣe amí ilẹ̀ náà.” Àwọn ọkùnrin náà sì lọ ṣe amí ìlú Áì.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́