Jẹ́nẹ́sísì 12:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Lẹ́yìn náà, Ábúrámù kó kúrò níbẹ̀, ó sì gba ọ̀nà Négébù+ lọ, ó ń pa àgọ́ láti ibì kan dé ibòmíì. Jẹ́nẹ́sísì 20:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Ábúráhámù wá ṣí ibùdó rẹ̀ kúrò níbẹ̀+ lọ sí ilẹ̀ Négébù, ó sì ń gbé láàárín Kádéṣì+ àti Ṣúrì.+ Nígbà tó ń gbé* ní Gérárì,+
20 Ábúráhámù wá ṣí ibùdó rẹ̀ kúrò níbẹ̀+ lọ sí ilẹ̀ Négébù, ó sì ń gbé láàárín Kádéṣì+ àti Ṣúrì.+ Nígbà tó ń gbé* ní Gérárì,+