-
Jẹ́nẹ́sísì 26:1, 2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
26 Ìyàn mú ní ilẹ̀ náà, yàtọ̀ sí ìyàn tó kọ́kọ́ mú nígbà ayé Ábúráhámù.+ Ísákì lọ sọ́dọ̀ Ábímélékì ọba àwọn Filísínì, ní Gérárì. 2 Jèhófà sì fara hàn án, ó sọ pé: “Má lọ sí Íjíbítì. Máa gbé ní ilẹ̀ tí mo fún ọ.
-