Jẹ́nẹ́sísì 12:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ìyàn wá mú ní ilẹ̀ náà, Ábúrámù sì gbéra lọ sí Íjíbítì kó lè gbé ibẹ̀ fúngbà díẹ̀,*+ torí ìyàn mú gidigidi ní ilẹ̀ náà.+
10 Ìyàn wá mú ní ilẹ̀ náà, Ábúrámù sì gbéra lọ sí Íjíbítì kó lè gbé ibẹ̀ fúngbà díẹ̀,*+ torí ìyàn mú gidigidi ní ilẹ̀ náà.+