-
Jẹ́nẹ́sísì 20:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 Ìgbà náà ni Ábímélékì mú àwọn àgùntàn àti màlúù pẹ̀lú àwọn ìránṣẹ́ lọ́kùnrin àti lóbìnrin, ó kó wọn fún Ábúráhámù, ó sì dá Sérà ìyàwó rẹ̀ pa dà fún un.
-