ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jẹ́nẹ́sísì 12:15, 16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 Àwọn ìjòyè Fáráò pẹ̀lú rí i, wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí í ròyìn rẹ̀ dáadáa fún Fáráò, débi pé wọ́n mú obìnrin náà lọ sí ilé Fáráò. 16 Fáráò tọ́jú Ábúrámù dáadáa nítorí obìnrin náà, Ábúrámù sì wá ní àwọn àgùntàn, màlúù, akọ àti abo kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́, àwọn ìránṣẹ́ lọ́kùnrin àti lóbìnrin àti àwọn ràkúnmí.+

  • Jẹ́nẹ́sísì 13:2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 2 Ábúrámù ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹran ọ̀sìn, fàdákà àti wúrà.+

  • Jẹ́nẹ́sísì 24:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 24 Ábúráhámù ti wá darúgbó, ó ti lọ́jọ́ lórí, Jèhófà sì ti bù kún Ábúráhámù ní gbogbo ọ̀nà.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́