Jẹ́nẹ́sísì 12:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Màá mú kí o di orílẹ̀-èdè ńlá, màá sì bù kún ọ. Màá mú kí orúkọ rẹ di ńlá, ó sì máa jẹ́ ìbùkún.+ Jẹ́nẹ́sísì 15:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Lẹ́yìn èyí, Jèhófà sọ fún Ábúrámù nínú ìran pé: “Ábúrámù, má bẹ̀rù.+ Apata ni mo jẹ́ fún ọ.+ Èrè rẹ yóò pọ̀ gan-an.”+ Jẹ́nẹ́sísì 15:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ó wá mú un wá sí ìta, ó sì sọ pé: “Jọ̀ọ́, gbójú sókè wo ọ̀run, kí o sì ka àwọn ìràwọ̀, tí o bá lè kà á.” Ó sì sọ fún un pé: “Bí ọmọ* rẹ á ṣe pọ̀ nìyẹn.”+ Ẹ́kísódù 1:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì* ń bímọ, wọ́n sì ń pọ̀ sí i, wọ́n ń bí sí i, wọ́n sì túbọ̀ ń lágbára gidigidi, débi pé wọ́n kún ilẹ̀ náà.+ Hébérù 11:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Torí èyí, nípasẹ̀ ọkùnrin kan tó ti ń kú lọ,+ a bí àwọn ọmọ + tó pọ̀ bí ìràwọ̀ ojú ọ̀run, tí wọn ò sì ṣeé kà bí iyanrìn etí òkun.+
15 Lẹ́yìn èyí, Jèhófà sọ fún Ábúrámù nínú ìran pé: “Ábúrámù, má bẹ̀rù.+ Apata ni mo jẹ́ fún ọ.+ Èrè rẹ yóò pọ̀ gan-an.”+
5 Ó wá mú un wá sí ìta, ó sì sọ pé: “Jọ̀ọ́, gbójú sókè wo ọ̀run, kí o sì ka àwọn ìràwọ̀, tí o bá lè kà á.” Ó sì sọ fún un pé: “Bí ọmọ* rẹ á ṣe pọ̀ nìyẹn.”+
7 Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì* ń bímọ, wọ́n sì ń pọ̀ sí i, wọ́n ń bí sí i, wọ́n sì túbọ̀ ń lágbára gidigidi, débi pé wọ́n kún ilẹ̀ náà.+
12 Torí èyí, nípasẹ̀ ọkùnrin kan tó ti ń kú lọ,+ a bí àwọn ọmọ + tó pọ̀ bí ìràwọ̀ ojú ọ̀run, tí wọn ò sì ṣeé kà bí iyanrìn etí òkun.+