Jẹ́nẹ́sísì 10:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Ààlà àwọn ọmọ Kénáánì bẹ̀rẹ̀ láti Sídónì títí lọ dé Gérárì,+ nítòsí Gásà,+ títí lọ dé Sódómù, Gòmórà,+ Ádímà àti Sébóíímù,+ nítòsí Láṣà. Jẹ́nẹ́sísì 13:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Ábúrámù ń gbé ilẹ̀ Kénáánì, àmọ́ Lọ́ọ̀tì ń gbé láàárín àwọn ìlú tó wà ní agbègbè náà.+ Nígbà tó yá, ó pàgọ́ rẹ̀ sí tòsí Sódómù.
19 Ààlà àwọn ọmọ Kénáánì bẹ̀rẹ̀ láti Sídónì títí lọ dé Gérárì,+ nítòsí Gásà,+ títí lọ dé Sódómù, Gòmórà,+ Ádímà àti Sébóíímù,+ nítòsí Láṣà.
12 Ábúrámù ń gbé ilẹ̀ Kénáánì, àmọ́ Lọ́ọ̀tì ń gbé láàárín àwọn ìlú tó wà ní agbègbè náà.+ Nígbà tó yá, ó pàgọ́ rẹ̀ sí tòsí Sódómù.