Jẹ́nẹ́sísì 14:1, 2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Nígbà ayé Ámúráfélì ọba Ṣínárì,+ Áríókù ọba Élásárì, Kedoláómà+ ọba Élámù+ àti Tídálì ọba Góíímù, 2 àwọn ọba yìí bá Bérà ọba Sódómù+ jagun àti Bíṣà ọba Gòmórà,+ Ṣínábù ọba Ádímà, Ṣémébà ọba Sébóíímù+ àti ọba Bélà, ìyẹn Sóárì.
14 Nígbà ayé Ámúráfélì ọba Ṣínárì,+ Áríókù ọba Élásárì, Kedoláómà+ ọba Élámù+ àti Tídálì ọba Góíímù, 2 àwọn ọba yìí bá Bérà ọba Sódómù+ jagun àti Bíṣà ọba Gòmórà,+ Ṣínábù ọba Ádímà, Ṣémébà ọba Sébóíímù+ àti ọba Bélà, ìyẹn Sóárì.