Jẹ́nẹ́sísì 13:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Màá mú kí ọmọ* rẹ pọ̀ bí erùpẹ̀ ilẹ̀, tó fi jẹ́ pé tí ẹnikẹ́ni bá lè ka erùpẹ̀ ilẹ̀ ni wọ́n á tó lè ka+ ọmọ* rẹ. Róòmù 4:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 (Èyí bá ohun tó wà lákọsílẹ̀ mu pé: “Mo ti yàn ọ́ ṣe bàbá ọ̀pọ̀ orílẹ̀-èdè.”)+ Èyí jẹ́ lójú Ọlọ́run, ẹni tó ní ìgbàgbọ́ nínú rẹ̀, tó ń sọ òkú di ààyè, tó sì ń pe àwọn ohun tí kò sí bíi pé wọ́n wà.*
16 Màá mú kí ọmọ* rẹ pọ̀ bí erùpẹ̀ ilẹ̀, tó fi jẹ́ pé tí ẹnikẹ́ni bá lè ka erùpẹ̀ ilẹ̀ ni wọ́n á tó lè ka+ ọmọ* rẹ.
17 (Èyí bá ohun tó wà lákọsílẹ̀ mu pé: “Mo ti yàn ọ́ ṣe bàbá ọ̀pọ̀ orílẹ̀-èdè.”)+ Èyí jẹ́ lójú Ọlọ́run, ẹni tó ní ìgbàgbọ́ nínú rẹ̀, tó ń sọ òkú di ààyè, tó sì ń pe àwọn ohun tí kò sí bíi pé wọ́n wà.*