Diutarónómì 14:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Torí èèyàn mímọ́ lẹ jẹ́+ fún Jèhófà Ọlọ́run yín, Jèhófà sì ti yàn yín kí ẹ lè di èèyàn rẹ̀, ohun ìní rẹ̀ pàtàkì,* nínú gbogbo èèyàn tó wà láyé.+
2 Torí èèyàn mímọ́ lẹ jẹ́+ fún Jèhófà Ọlọ́run yín, Jèhófà sì ti yàn yín kí ẹ lè di èèyàn rẹ̀, ohun ìní rẹ̀ pàtàkì,* nínú gbogbo èèyàn tó wà láyé.+