Léfítíkù 19:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 “Sọ fún gbogbo àpéjọ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pé, ‘Kí ẹ jẹ́ mímọ́, torí èmi Jèhófà Ọlọ́run yín jẹ́ mímọ́.+ Léfítíkù 20:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Kí ẹ jẹ́ mímọ́ fún mi, torí èmi Jèhófà jẹ́ mímọ́,+ mo sì ń yà yín sọ́tọ̀ kúrò lára àwọn èèyàn yòókù kí ẹ lè di tèmi.+ Diutarónómì 28:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Jèhófà máa fi ọ́ ṣe èèyàn mímọ́ fún ara rẹ̀,+ bó ṣe búra fún ọ+ gẹ́lẹ́, torí pé ò ń pa àwọn àṣẹ Jèhófà Ọlọ́run rẹ mọ́, o sì ń rìn ní àwọn ọ̀nà rẹ̀. 1 Pétérù 1:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 àmọ́ bíi ti Ẹni Mímọ́ tó pè yín, kí ẹ̀yin náà di mímọ́ nínú gbogbo ìwà yín,+
2 “Sọ fún gbogbo àpéjọ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pé, ‘Kí ẹ jẹ́ mímọ́, torí èmi Jèhófà Ọlọ́run yín jẹ́ mímọ́.+
26 Kí ẹ jẹ́ mímọ́ fún mi, torí èmi Jèhófà jẹ́ mímọ́,+ mo sì ń yà yín sọ́tọ̀ kúrò lára àwọn èèyàn yòókù kí ẹ lè di tèmi.+
9 Jèhófà máa fi ọ́ ṣe èèyàn mímọ́ fún ara rẹ̀,+ bó ṣe búra fún ọ+ gẹ́lẹ́, torí pé ò ń pa àwọn àṣẹ Jèhófà Ọlọ́run rẹ mọ́, o sì ń rìn ní àwọn ọ̀nà rẹ̀.