Jẹ́nẹ́sísì 17:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Gbogbo ọkùnrin tí wọ́n bí ní ilé rẹ àti gbogbo ọkùnrin tí o fi owó rẹ rà gbọ́dọ̀ dádọ̀dọ́,*+ májẹ̀mú mi tó wà nínú ẹran ara yín gbọ́dọ̀ jẹ́ májẹ̀mú ayérayé.
13 Gbogbo ọkùnrin tí wọ́n bí ní ilé rẹ àti gbogbo ọkùnrin tí o fi owó rẹ rà gbọ́dọ̀ dádọ̀dọ́,*+ májẹ̀mú mi tó wà nínú ẹran ara yín gbọ́dọ̀ jẹ́ májẹ̀mú ayérayé.