Jóòbù 34:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Torí ó dájú pé, Ọlọ́run kì í hùwà burúkú;+Olódùmarè kì í sì í yí ìdájọ́ po.+ Àìsáyà 33:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Torí Jèhófà ni Onídàájọ́ wa,+Jèhófà ni Afúnnilófin wa,+Jèhófà ni Ọba wa;+Òun ni Ẹni tó máa gbà wá.+
22 Torí Jèhófà ni Onídàájọ́ wa,+Jèhófà ni Afúnnilófin wa,+Jèhófà ni Ọba wa;+Òun ni Ẹni tó máa gbà wá.+