Jẹ́nẹ́sísì 19:30 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 30 Nígbà tó yá, Lọ́ọ̀tì àti àwọn ọmọbìnrin rẹ̀ méjèèjì kúrò ní Sóárì, wọ́n sì lọ ń gbé ní agbègbè olókè,+ torí ẹ̀rù ń bà á láti máa gbé ní Sóárì.+ Ó wá lọ ń gbé inú ihò, pẹ̀lú àwọn ọmọ rẹ̀ méjèèjì. Sáàmù 68:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Ọlọ́run tòótọ́ ni Ọlọ́run tó ń gbà wá là;+Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ sì ń gbani lọ́wọ́ ikú.+
30 Nígbà tó yá, Lọ́ọ̀tì àti àwọn ọmọbìnrin rẹ̀ méjèèjì kúrò ní Sóárì, wọ́n sì lọ ń gbé ní agbègbè olókè,+ torí ẹ̀rù ń bà á láti máa gbé ní Sóárì.+ Ó wá lọ ń gbé inú ihò, pẹ̀lú àwọn ọmọ rẹ̀ méjèèjì.