Lúùkù 17:32 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 32 Ẹ rántí aya Lọ́ọ̀tì.+ Hébérù 10:38 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 38 “Àmọ́ ìgbàgbọ́ yóò mú kí olódodo mi wà láàyè”+ àti pé “tó bá fà sẹ́yìn, inú mi* ò ní dùn sí i.”+