Jẹ́nẹ́sísì 19:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Bí wọ́n ṣe mú wọn dé ẹ̀yìn odi, ó sọ pé: “Ẹ sá àsálà fún ẹ̀mí* yín! Ẹ má wo ẹ̀yìn,+ ẹ má sì dúró níbikíbi ní agbègbè yìí!+ Ẹ sá lọ sí agbègbè olókè kí ẹ má bàa pa run!” Jẹ́nẹ́sísì 19:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Àmọ́ ìyàwó Lọ́ọ̀tì tó wà lẹ́yìn rẹ̀ bẹ̀rẹ̀ sí í wo ẹ̀yìn, ó sì di ọwọ̀n* iyọ̀.+
17 Bí wọ́n ṣe mú wọn dé ẹ̀yìn odi, ó sọ pé: “Ẹ sá àsálà fún ẹ̀mí* yín! Ẹ má wo ẹ̀yìn,+ ẹ má sì dúró níbikíbi ní agbègbè yìí!+ Ẹ sá lọ sí agbègbè olókè kí ẹ má bàa pa run!”