Jẹ́nẹ́sísì 10:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Ààlà àwọn ọmọ Kénáánì bẹ̀rẹ̀ láti Sídónì títí lọ dé Gérárì,+ nítòsí Gásà,+ títí lọ dé Sódómù, Gòmórà,+ Ádímà àti Sébóíímù,+ nítòsí Láṣà. Jẹ́nẹ́sísì 26:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ísákì sì ń gbé ní Gérárì.+
19 Ààlà àwọn ọmọ Kénáánì bẹ̀rẹ̀ láti Sídónì títí lọ dé Gérárì,+ nítòsí Gásà,+ títí lọ dé Sódómù, Gòmórà,+ Ádímà àti Sébóíímù,+ nítòsí Láṣà.