-
Jẹ́nẹ́sísì 26:9, 10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 Ni Ábímélékì bá pe Ísákì, ó sì sọ pé: “Ìyàwó rẹ ni obìnrin yìí! Kí nìdí tó o fi sọ pé, ‘Àbúrò mi ni’?” Ísákì wá fèsì pé: “Ẹ̀rù ló bà mí, kí n má bàa kú torí rẹ̀+ ni mo ṣe sọ bẹ́ẹ̀.” 10 Àmọ́ Ábímélékì sọ pé: “Kí lo ṣe sí wa yìí?+ Ọ̀kan nínú àwọn èèyàn yìí ì bá ti bá ìyàwó rẹ sùn, o ò bá sì ti mú ká jẹ̀bi!”+
-