-
Jẹ́nẹ́sísì 16:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 Ábúrámù wá bá Hágárì ní àṣepọ̀, ó sì lóyún. Nígbà tó rí i pé òun ti lóyún, ó bẹ̀rẹ̀ sí í fojú àbùkù wo Sáráì ọ̀gá rẹ̀.
-
-
Jẹ́nẹ́sísì 16:15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 Hágárì wá bí ọmọkùnrin kan fún Ábúrámù, Ábúrámù sì pe orúkọ ọmọ tí Hágárì bí fún un ní Íṣímáẹ́lì.+
-