Jẹ́nẹ́sísì 21:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Àmọ́ Sérà ń kíyè sí i pé ọmọ tí Hágárì+ ará Íjíbítì bí fún Ábúráhámù ń fi Ísákì ṣe yẹ̀yẹ́.+ Gálátíà 4:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Bí àpẹẹrẹ, ó wà lákọsílẹ̀ pé Ábúráhámù ní ọmọkùnrin méjì, ọ̀kan látọ̀dọ̀ ìránṣẹ́bìnrin,+ èkejì látọ̀dọ̀ obìnrin tó lómìnira;+ Gálátíà 4:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 A lè fi àwọn nǹkan yìí ṣe àkàwé; àwọn obìnrin yìí dúró fún májẹ̀mú méjì, èyí tó wá láti Òkè Sínáì,+ tó ń bí ọmọ fún ìsìnrú, ni Hágárì.
22 Bí àpẹẹrẹ, ó wà lákọsílẹ̀ pé Ábúráhámù ní ọmọkùnrin méjì, ọ̀kan látọ̀dọ̀ ìránṣẹ́bìnrin,+ èkejì látọ̀dọ̀ obìnrin tó lómìnira;+
24 A lè fi àwọn nǹkan yìí ṣe àkàwé; àwọn obìnrin yìí dúró fún májẹ̀mú méjì, èyí tó wá láti Òkè Sínáì,+ tó ń bí ọmọ fún ìsìnrú, ni Hágárì.