Jẹ́nẹ́sísì 15:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ó wá sọ fún Ábúrámù pé: “Mọ̀ dájú pé àwọn ọmọ* rẹ máa di àjèjì ní ilẹ̀ tí kì í ṣe tiwọn, àwọn èèyàn ibẹ̀ á fi wọ́n ṣe ẹrú, wọ́n á sì fìyà jẹ wọ́n fún ọgọ́rùn-ún mẹ́rin (400) ọdún.+ Gálátíà 4:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Bí àpẹẹrẹ, ó wà lákọsílẹ̀ pé Ábúráhámù ní ọmọkùnrin méjì, ọ̀kan látọ̀dọ̀ ìránṣẹ́bìnrin,+ èkejì látọ̀dọ̀ obìnrin tó lómìnira;+ Gálátíà 4:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Àmọ́ bó ṣe rí nígbà yẹn tí èyí tí a bí lọ́nà ti ẹ̀dá* bẹ̀rẹ̀ sí í ṣe inúnibíni sí èyí tí a bí lọ́nà ti ẹ̀mí,+ bẹ́ẹ̀ náà ló ṣe rí ní báyìí.+
13 Ó wá sọ fún Ábúrámù pé: “Mọ̀ dájú pé àwọn ọmọ* rẹ máa di àjèjì ní ilẹ̀ tí kì í ṣe tiwọn, àwọn èèyàn ibẹ̀ á fi wọ́n ṣe ẹrú, wọ́n á sì fìyà jẹ wọ́n fún ọgọ́rùn-ún mẹ́rin (400) ọdún.+
22 Bí àpẹẹrẹ, ó wà lákọsílẹ̀ pé Ábúráhámù ní ọmọkùnrin méjì, ọ̀kan látọ̀dọ̀ ìránṣẹ́bìnrin,+ èkejì látọ̀dọ̀ obìnrin tó lómìnira;+
29 Àmọ́ bó ṣe rí nígbà yẹn tí èyí tí a bí lọ́nà ti ẹ̀dá* bẹ̀rẹ̀ sí í ṣe inúnibíni sí èyí tí a bí lọ́nà ti ẹ̀mí,+ bẹ́ẹ̀ náà ló ṣe rí ní báyìí.+