-
Jẹ́nẹ́sísì 26:15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 Torí náà, àwọn Filísínì rọ iyẹ̀pẹ̀ dí gbogbo kànga tí àwọn ìránṣẹ́ Ábúráhámù+ bàbá rẹ̀ gbẹ́ nígbà ayé rẹ̀.
-
-
Jẹ́nẹ́sísì 26:20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
20 Àwọn olùṣọ́ àgùntàn Gérárì wá bẹ̀rẹ̀ sí í bá àwọn olùṣọ́ àgùntàn Ísákì jà, wọ́n ń sọ pé: “Omi wa ni!” Torí náà, ó pe orúkọ kànga náà ní Ésékì,* torí wọ́n bá a jà.
-