-
Jẹ́nẹ́sísì 26:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
26 Ìyàn mú ní ilẹ̀ náà, yàtọ̀ sí ìyàn tó kọ́kọ́ mú nígbà ayé Ábúráhámù.+ Ísákì lọ sọ́dọ̀ Ábímélékì ọba àwọn Filísínì, ní Gérárì.
-