Jẹ́nẹ́sísì 12:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Jèhófà sì sọ fún Ábúrámù pé: “Kúrò ní ilẹ̀ rẹ, kí o kúrò lọ́dọ̀ àwọn mọ̀lẹ́bí rẹ àti ilé bàbá rẹ, kí o lọ sí ilẹ̀ tí màá fi hàn ọ́.+ Hébérù 11:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Ìgbàgbọ́ mú kí Ábúráhámù+ ṣègbọràn nígbà tí a pè é, ó lọ sí ibì kan tó máa gbà, tó sì máa jogún; ó jáde lọ, bí kò tiẹ̀ mọ ibi tó ń lọ.+
12 Jèhófà sì sọ fún Ábúrámù pé: “Kúrò ní ilẹ̀ rẹ, kí o kúrò lọ́dọ̀ àwọn mọ̀lẹ́bí rẹ àti ilé bàbá rẹ, kí o lọ sí ilẹ̀ tí màá fi hàn ọ́.+
8 Ìgbàgbọ́ mú kí Ábúráhámù+ ṣègbọràn nígbà tí a pè é, ó lọ sí ibì kan tó máa gbà, tó sì máa jogún; ó jáde lọ, bí kò tiẹ̀ mọ ibi tó ń lọ.+