Jẹ́nẹ́sísì 11:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Térà pé ẹni àádọ́rin (70) ọdún, ó sì bí Ábúrámù,+ Náhórì+ àti Háránì.