-
Jẹ́nẹ́sísì 24:17Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
17 Ni ìránṣẹ́ náà bá sáré lọ bá a, ó sì sọ pé: “Jọ̀ọ́, fún mi ní omi díẹ̀ mu látinú ìṣà omi rẹ.”