ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jẹ́nẹ́sísì 37:28
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 28 Nígbà tí àwọn oníṣòwò tí wọ́n jẹ́ ọmọ Mídíánì+ ń kọjá lọ, wọ́n fa Jósẹ́fù jáde látinú kòtò omi náà, wọ́n sì tà á fún àwọn ọmọ Íṣímáẹ́lì ní ogún (20) ẹyọ fàdákà.+ Ni àwọn ọkùnrin yìí bá mú Jósẹ́fù lọ sí Íjíbítì.

  • Ẹ́kísódù 2:15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 Lẹ́yìn náà, Fáráò gbọ́ ohun tó ṣẹlẹ̀, ó sì fẹ́ pa Mósè; àmọ́ Mósè sá lọ torí Fáráò, ó sì lọ ń gbé ní ilẹ̀ Mídíánì.+ Nígbà tó dé ibẹ̀, ó jókòó sẹ́gbẹ̀ẹ́ kànga kan.

  • Nọ́ńbà 31:2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 2 “Gbẹ̀san+ lára àwọn ọmọ Mídíánì+ torí ohun tí wọ́n ṣe fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì. Lẹ́yìn náà, a máa kó ọ jọ pẹ̀lú àwọn èèyàn rẹ.”*+

  • Àwọn Onídàájọ́ 6:2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 2 Mídíánì wá ń jọba lé Ísírẹ́lì lórí.+ Torí Mídíánì, àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ṣe àwọn ibi tí wọ́n lè sá pa mọ́ sí* nínú àwọn òkè, nínú àwọn ihò àti láwọn ibi tó ṣòroó dé.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́