Jẹ́nẹ́sísì 25:1, 2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Ábúráhámù fẹ́ ìyàwó míì, Kétúrà ni orúkọ rẹ̀. 2 Nígbà tó yá, ó bí Símíránì, Jókíṣánì, Médánì, Mídíánì,+ Íṣíbákì àti Ṣúáhì.+ Ẹ́kísódù 3:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Mósè ń bójú tó agbo ẹran Jẹ́tírò+ bàbá ìyàwó rẹ̀ tó jẹ́ àlùfáà Mídíánì. Nígbà tó ń da agbo ẹran náà lọ sí apá ìwọ̀ oòrùn aginjù, ó dé Hórébù, òkè Ọlọ́run tòótọ́.+ Ẹ́kísódù 4:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Lẹ́yìn náà, Jèhófà sọ fún Mósè ní Mídíánì pé: “Pa dà lọ sí Íjíbítì, torí gbogbo àwọn tó fẹ́ pa ọ́* ti kú.”+
25 Ábúráhámù fẹ́ ìyàwó míì, Kétúrà ni orúkọ rẹ̀. 2 Nígbà tó yá, ó bí Símíránì, Jókíṣánì, Médánì, Mídíánì,+ Íṣíbákì àti Ṣúáhì.+
3 Mósè ń bójú tó agbo ẹran Jẹ́tírò+ bàbá ìyàwó rẹ̀ tó jẹ́ àlùfáà Mídíánì. Nígbà tó ń da agbo ẹran náà lọ sí apá ìwọ̀ oòrùn aginjù, ó dé Hórébù, òkè Ọlọ́run tòótọ́.+
19 Lẹ́yìn náà, Jèhófà sọ fún Mósè ní Mídíánì pé: “Pa dà lọ sí Íjíbítì, torí gbogbo àwọn tó fẹ́ pa ọ́* ti kú.”+